📖 Ìtàn — Story Time!

Read in Yorùbá first, then tap the magic button to reveal the English!

Sefunmi and her friend at the market

Ìtàn 1: Ṣèfúnmí àti Ọrẹ Rẹ̀

Ṣèfúnmí lọ sí ọjà pẹ̀lú ọrẹ rẹ̀. Wọ́n ra ounjẹ àti omi. Wọ́n rẹrin-in, wọ́n yọ̀, wọ́n jó. Ó jẹ́ ọjọ́ to dara!

✨ Sefunmi went to the market with her friend. They bought food and water. They laughed, celebrated, and danced. It was a beautiful day!
Tortoise and goat sharing grass

Ìtàn 2: Ijàpá àti Ewúrẹ́

Ijàpá fẹ́ jẹun. Ó rí ewúrẹ́ tó ń jẹ koríko. Ó wí pé, “Jẹ́ ká pin in.” Ewúrẹ́ rẹrin-in, ó sì gbà.

✨ Tortoise was hungry. He saw a goat eating grass. He said, “Let's share it.” The goat laughed and agreed.
Sefunmi learning at school

Ìtàn 3: Ọjọ́ Ikẹta Ṣèfúnmí ní Ilé Ẹ̀kọ́

Lọ́jọ́ ikẹta rẹ ní ilé ẹ̀kọ́, Ṣèfúnmí kẹ́kọ̀ọ́ nípa ara. Wọ́n kọ́ ọ ní, “Ọwọ́, ẹsẹ̀, ojú, etí…” Ó gbádùn ẹ̀kọ́ naa!

✨ On her third day at school, Sefunmi learned about the body. They taught her: “Hand, leg, eyes, ears…” She enjoyed the lesson!

Story pictures were made with Google Gemini.